Títù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbà wá là. Kì í ṣe nípa iṣẹ́ tí àwa ṣe nínú òdodo bí kò ṣe nítorí àánú rẹ̀. Ó gbà wá là, nípaṣẹ̀ ìwẹ̀nù àtúnbí àti ìsọdọ̀tun ti Ẹ̀mí Mímọ́,

Títù 3

Títù 3:2-11