Títù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ́ àwọn ẹrú láti se ìgbọ́ran sí àwọn olówó wọn nínú ohun gbogbo, láti máa gbìyànjú láti tẹ́ wọn lọ́rùn, wọn kò gbọdọ̀ gbó olówó wọn lẹ́nu,

Títù 2

Títù 2:7-15