Títù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń kọ́ wa láti sẹ́ àìwà-bí Ọlọ́run àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ayé, kí a gbé ìgbé ayé ìkóra-ẹni-ní-ìjánu, ìdúrósinsin àti ìwà-bí-Ọlọ́run ní ayé ìsínsìnyìí,

Títù 2

Títù 2:3-13