Títù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alámójútó jẹ́ ẹni tí a gbé iṣẹ́ Ọlọ́run lé lọ́wọ́, nítorí náà, kò gbọdọ̀ ní àbùkù kankan tàbí agbéraga, oníjà, kò gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀mùtí tàbí alágídí tàbí olójúkòkòrò.

Títù 1

Títù 1:1-16