Títù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìgbàgbọ́ àti ìmọ̀ tí ó dúró lórí ìrètí iyè àìnípẹ̀kun, èyí tí Ọlọ́run tí kì í purọ́ ti se ìlérí rẹ̀ ṣáájú kí ayé tó bẹ̀rẹ̀,

Títù 1

Títù 1:1-6