Sekaráyà 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n, Olúwa yóò kó gbogbo ohun ìní rẹ̀ lọ,yóò sì pa agbára rẹ̀ run ní ojú òkun,a ó sì fi iná jó o run.

Sekaráyà 9

Sekaráyà 9:1-10