Sekaráyà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé: “Kiyesi i, èmi ó gba àwọn ènìyàn mi kúrò ni ilẹ̀ ìlà-oòrùn, àti kúrò ni ilẹ̀ ìwọ̀-oòrùn.

Sekaráyà 8

Sekaráyà 8:6-10