Sekaráyà 8:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́ ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn àti àwọn alágbára orílẹ̀-èdè yóò wá láti wá Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní Jérúsálẹ́mù; àti láti gbàdúrà, àti láti wá ojú rere Olúwa.”

Sekaráyà 8

Sekaráyà 8:17-23