Sekaráyà 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni nǹkan tí ẹ̀yin ó ṣe: Ẹ ṣọ̀rọ̀ òtítọ́, olúkúlúkù sí ẹnikejì rẹ̀; ṣe ìdájọ́ tòótọ́ àti àlàáfíà ní àwọn ibodè yín.

Sekaráyà 8

Sekaráyà 8:6-23