Sekaráyà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọwọ́ Serubábélì ni a ti ṣe ipilẹ̀ ilé yìí, ọwọ́ rẹ̀ ni yóò sì parí rẹ̀; ìwọ yóò sì mọ̀ pé, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni ó rán mi sí i yín.

Sekaráyà 4

Sekaráyà 4:7-12