Sekaráyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì kiyesí i, ańgẹ́li tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀ jáde lọ, ańgẹ́lì mìíràn si jáde lọ pade rẹ̀.

Sekaráyà 2

Sekaráyà 2:1-10