Sekaráyà 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ṣe, olúkúlùkù ẹni tí o kù nínú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí ó dìde sí Jérúsálẹ́mù yóò máa gòkè lọ lọ́dọọdún láti sìn Ọba, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, àti láti ṣe àjọyọ̀ àṣè àgọ́ náà.

Sekaráyà 14

Sekaráyà 14:8-17