Sekaráyà 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ṣe ni ọjọ́ náà, èmi yóò wá láti pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè run tí ó wá kọjú ìjà sí Jérúsálẹ́mù.”

Sekaráyà 12

Sekaráyà 12:2-14