Sekaráyà 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa pẹ̀lú yóò kọ́ tètè gba àgọ́ Júdà là ná, kí ògo ilé Dáfídì àti ògo àwọn ara Jérúsálẹ́mù má ba gbé ara wọn ga sí Júdà.

Sekaráyà 12

Sekaráyà 12:1-14