Sekaráyà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí, “Ni èmi yóò fí ìdágìrì lu gbogbo ẹṣin, àti fi òmùgọ̀ kọlu ẹni tí ń gun un; èmi yóò sì sí ojú mi sí ilé Júdà, èmi yóò sì bu ìfọ́jú lu gbogbo ẹṣin tí orílẹ̀-èdè.

Sekaráyà 12

Sekaráyà 12:1-6