Sefanáyà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ti mú ìdájọ́ rẹ wọ̀n-ọn-nìkúrò, ó sì ti ti àwọn ọ̀ta rẹ padà sẹ́yìn. Olúwa, ọba Ísírẹ́lì wà pẹ̀lú rẹ,Ìwọ kì yóò sì bẹ̀rù ibi kan mọ́.

Sefanáyà 3

Sefanáyà 3:9-20