Sefanáyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ti gbọ́ ẹ̀gàn Móábù,àti ẹlẹ́yà àwọn Ámónì,àwọn tó kẹ́gàn àwọn ènìyàn mi,tí wọ́n sì ti gbé ara wọn ga sí agbègbè wọn.

Sefanáyà 2

Sefanáyà 2:1-13