Sefanáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti àwọn tí wọn ń foríbalẹ̀ tí wọnń sin ogun ọ̀run lórí òrùlé.Àwọn tí wọn ń sìn, tí wọ́n sì ń fi Olúwa búra,tí wọ́n sì ń fi Mólékì búra.

Sefanáyà 1

Sefanáyà 1:1-7