Sefanáyà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni fàdákà tàbí wúrà wọnkì yóò sì le gbà wọ́n làní ọjọ́ ìbínú Olúwa.Ṣùgbọ́n gbogbo ayé ni a ó fi ináìjowú rẹ̀ parun,nítorí òun yóò fi ìyára fi òpin sígbogbo àwọn tí ń gbé ní ilé ayé.”

Sefanáyà 1

Sefanáyà 1:8-18