Sáàmù 97:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iná ń jó níwájú Rẹ̀. O sì ń jó àwọn ọ̀ta Rẹ̀ yíká kiri

Sáàmù 97

Sáàmù 97:1-7