Sáàmù 96:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa sin Olúwa ninú ẹwà ìwà mímọ́ Rẹ̀;ẹ wárìrì níwájú Rẹ̀ gbogbo ayé.

Sáàmù 96

Sáàmù 96:1-13