Sáàmù 95:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a forí balẹ̀ kí a sìn-ín,Ẹ jẹ́ kí a kúnlẹ̀ níwájú Olúwa ẹni tí ó dá wa;

Sáàmù 95

Sáàmù 95:1-11