Sáàmù 92:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti fihàn pé “Ẹni ìdúró ṣinṣin ni Olúwa;òun ni àpáta mi, kò sì sí aburúkankan nínú Rẹ̀”

Sáàmù 92

Sáàmù 92:7-15