Sáàmù 92:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olódodo yóò gbèrú bí i igi ọ̀pẹ,wọn yóò dàgbà bí i igi kédárì Lẹ́bánónì;

Sáàmù 92

Sáàmù 92:4-15