Sáàmù 91:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹgbẹ̀rún yóò ṣubú ní ẹ̀gbẹ́ Rẹ,ẹgbàarùn ún ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹṣùgbọ́n kì yóò sún mọ́ ọ̀dọ̀ Rẹ

Sáàmù 91

Sáàmù 91:1-16