Sáàmù 91:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò rìn lórí kìnnìún àti paramọ́lẹ̀;ìwọ yóò tẹ kìnnìún ńlá àti ejò nì ìwọ yóò fi ẹsẹ̀ tẹ̀ mọ́lẹ̀

Sáàmù 91

Sáàmù 91:7-16