Sáàmù 90:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìrán dé ìran.

2. Kí a to bí àwọn òkè nlaàti kí ìwọ tó dá ilẹ̀ àti ayé,láti ayérayé dé ayérayé ìwọ ni Ọlọ́run.

Sáàmù 90