Sáàmù 9:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìparun àìlópin ti borí àwọn ọ̀ta,Ìwọ ti fa àwọn ìlú wọn tu;Àní ìrántí wọn sì ti sègbé.

Sáàmù 9

Sáàmù 9:1-9