Sáàmù 89:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa?Tí ìwọ ó ha fi ara Rẹ pamọ́ títí láé?Yóò ti pẹ́ to tí ìbínú Rẹ yóò máa jó bí iná?

Sáàmù 89

Sáàmù 89:39-50