Sáàmù 89:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò kígbe sí mi pé, ‘ìwọ ní bàbá mi, Ọlọ́run mi, àti àpáta ìgbàlà mi!’

Sáàmù 89

Sáàmù 89:25-35