Sáàmù 89:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kọrin títóbi ìfẹ́ Olúwa títí láé;pẹ̀lú ẹnu mi ní èmi yóò jẹ́ kí a mọ̀ òtítọ́ Rẹ láti ìran dé ìran.

Sáàmù 89

Sáàmù 89:1-7