Sáàmù 88:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú mi káànú nítorí ìpọ́njú.Mo kígbe pè ọ́, Olúwa, ní gbogbo ọjọ́;mo na ọwọ́ mí jáde sí ọ.

Sáàmù 88

Sáàmù 88:2-13