Sáàmù 88:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n mo kígbe sí ọ fún ìrànlọ́wọ́, Olúwa;ní òwúrọ̀ ní àdúrà mí wá sọ́dọ̀ Rẹ.

Sáàmù 88

Sáàmù 88:4-18