Sáàmù 87:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn olorin àti àwọn ti ń luohun èlò orin yóò wí pé,“Gbogbo orísun mi ń bẹ nínú Rẹ.”

Sáàmù 87

Sáàmù 87:1-7