Sáàmù 86:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáàbòbò ayé mi, nítorí a ti yà mí sọ́tọ̀ fún ọ:ìwọ ní Ọlọ́run mi,gbà ìránṣẹ́ Rẹ làtí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ.

Sáàmù 86

Sáàmù 86:1-12