Sáàmù 86:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi o yìn ọ, Olúwa Ọlọ́run mi, pẹ̀lú gbogbo ọkan mi;èmi o fògo fún orúkọ Rẹ títí láé

Sáàmù 86

Sáàmù 86:7-16