Sáàmù 85:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò ha máa bínú sí wa títí láé?Ìwọ yóò ha mú ìbínú Rẹ pẹ́ yìí gbogbo ìran ká?

Sáàmù 85

Sáàmù 85:4-8