Sáàmù 85:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìwọ fi ojú rere han fún ilé Rẹ, Olúwa;ìwọ mú ohun ìní Jákọ́bù bọ̀ sí pò.

2. Ìwọ dárí àìṣedédé àwọn ènìyàn Rẹ̀ jìnìwọ sì bó ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀. Sela

Sáàmù 85