Sáàmù 83:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. fi ìtìjú kún ojú wọnkí àwọn ènìyàn báà lè ṣe àfẹ́rí orúkọ Rẹ àti kí o fí ìjì líle Rẹ dẹ́rùbà ìwọ Olúwa.

17. Jẹ́ kí ojú kí ó ti wọn, kí wọ́n sì dáámù láéláékí wọ́n ṣègbé sínú ẹ̀gàn

18. Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ, tí orúkọ Rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa:pé ìwọ níkan ní Ọ̀gá-ògo jùlọ lórí gbogbo ayé.

Sáàmù 83