Sáàmù 81:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìnilára ni ẹ pè mo sì gbà yín là,mo dá a yín lóhùn nínú ìkọ̀kọ̀ àrá,mo dán an yín wò ní odò Méríbà. Sela

Sáàmù 81

Sáàmù 81:1-14