Sáàmù 81:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni Olúwa Ọlọ́run Rẹ,ẹni tí ó mú un yín jáde láti Éjíbítì.Ẹ la ẹnu yín gbòòrò, èmi yóò sì kún un.

Sáàmù 81

Sáàmù 81:4-16