Sáàmù 80:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A gé àjàrà Rẹ lulẹ̀, a ti fi iná sun ún;ní ìfibú, àwọn ènìyàn Rẹ̀ ń ṣègbé.

Sáàmù 80

Sáàmù 80:13-19