Sáàmù 80:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yípadà sí wa, àwa ń bẹ̀ ọ, Ọlọ́run!Bo jú wolẹ̀ láti ọ̀run kí o sì wò ó!Kí o sì bẹ àjàrà yìí wò,

Sáàmù 80

Sáàmù 80:4-19