Sáàmù 79:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ti fi ara òkú àwọn ìránṣẹ́ Rẹ̀fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run ní oúnjẹ,ẹran ara àwọn ènìyàn mímọ́ Rẹ̀ fún ẹranko ilẹ̀.

Sáàmù 79

Sáàmù 79:1-10