Sáàmù 79:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà àwa ènìyàn Rẹ,àgùntàn pápá Rẹ,yóò fi ọpẹ́ fún ọ títí láé;láti ìran dé ìranni àwa ó fi ìyìn Rẹ hàn.

Sáàmù 79

Sáàmù 79:9-13