Sáàmù 79:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí ìmí ẹ̀dùn oǹdè náà wá ṣíwájú Rẹ,gẹ́gẹ́ bí títóbi agbára Rẹìwọ ṣe ìtọ́jú àwọn ti a dá lẹ́bí ikú.

Sáàmù 79

Sáàmù 79:1-12