Sáàmù 78:69-72 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

69. Ó kọ́ ibi mímọ́ Rẹ̀, ibí gíga,gẹ́gẹ́ bí ayé tí ó fi ìdí Rẹ̀ múlẹ̀ títí láé.

70. Ó yan Dáfídì ìránṣẹ́ Rẹ̀ó mú láti inú àwọn agbo ẹran;

71. Ó mú un jáde nínú ìtọ́jú àgùntànláti jẹ́ olùṣọ́ Àgùntàn àwọn ènìyàn Rẹ̀ Jákọ́bùàti Ísírẹ́lì ogún un Rẹ̀.

72. Dáfídì sì ṣọ wọn pẹ̀lú òtítọ́ inú ọkàn;pẹ̀lú ọwọ́ òye ní ó fi darí wọn.

Sáàmù 78