Sáàmù 78:62 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi àwọn ènìyàn Rẹ̀ lé idà lọ́wọ́,ó sì bínú sí àwọn ohun ìní Rẹ̀.

Sáàmù 78

Sáàmù 78:54-69