Sáàmù 78:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rọ ọ̀jọ̀ ẹran sílẹ̀ sórí wọn bí erùpẹ̀ ilẹ̀,àti ẹyẹ abìyẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìyànrìn etí òkun

Sáàmù 78

Sáàmù 78:22-31