Sáàmù 78:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọ̀ṣán ó fi ìkúùku àwọsánmọ̀ ṣe amọ̀nà wọnàti ní gbogbo òru pẹ̀lú, ìmọ̀lẹ̀ ìná.

Sáàmù 78

Sáàmù 78:11-17